News

Senito Ibikunle Amosun lu Oloogbe Otunba Micheal Olasubomi Balogun Logo Enu

Gomina teleri ni ipinle Ogun to tun je asofin to n soju aarin gbungbun ipinle Ogun nile asofin agba, Ibikunle Amosun ti daro ipapoda Oloogbe Olasubomi Balogun, eni to dagbere faye ni ojo eti kokandinlogbon osu karun Odun 2023 yii leni Odun mokandinlaadorin.

Atejade ti Senito Amosun fowosi sapejuwe Oloogbe naa ti tun se Olori Omooba ile Ijebu gegebi akinkanju omo orile ede yii, Oluda Ile Ifowopamosi sile, Olokowo ti ko se fowo ro seyin, Olugbe asa ga, oninu didun Olore, to ti bale to si lapa rere.

Gomina teleri ohun wa kedun pelu iyawo Oloogbe, Olori Abimbola Balogun, awon omo, awon ebi, awujale ti Ijebu, gbogbo idile olomooba nile Ijebu ati gbogbo awon to selede leyin re.

O wa gba adura pe ki Olorun te Otunba Olasubomi Balogun si afefe rere.

For more stories, please visit our website – www.ntaabeokuta.com.ng;   YouTube channel – NTA Abeokuta News;   Facebook Page – @NTAABEOKUTACHANNEL12 and  Instagram – @ntaabeokuta1979

Show More

Related Articles

Leave a Reply

Your email address will not be published.

Back to top button