News

Gomina Abiodun Ni Ijoba Ipinle Ogun yoo Sagbateru Isinku Oloogbe Diya

May be an image of 3 people, people sitting and indoor

Gomina Ipinle Ogun, Dapo Abiodun ti salaye pe eto isinku alarinrin ni won yoo se fun Olori apapo ile ise ologun orile ede yii teleri, Ogagun agba Oladipo Diya.

Gomina salaye oro yii lakoko to ko awon igbimo alase ipinle ogun lo sabewo ibanikedun si awon ebi oloogbe naa to wa ni ile re to wa ni ipinle eko

Gomina Abiodun sapejuwe iku oloogbw diya gegge bi adanu nla fun ipinle ogun ati orile ede yi lapapo, pelu afikun pe oloogbe na gbe igbe aye to se apeere rere.

No photo description available.

O so di mimo pe Oloogbe yii gbe aye to ni itumo rere lati igba to ti wo ise ologun titi to fi di Olori apapo ile ise Ologun

Gomina so di mimo pe itan ipinle ko le pe lai daruko Oloogbe Diya

May be an image of 3 people, people standing, people sitting and outdoors

O salaye pe igbimo kan to je ti awon omo igbimo alase ipinle ogun yoo di gbigbe kale lati fikulukun pelu ebi Oloogbe lori eto isinku re

May be an image of 15 people, people sitting, people standing and indoor

For more stories, please visit our website – www.ntaabeokuta.com.ng;   YouTube channel – NTA Abeokuta News;   Facebook Page – @NTAABEOKUTACHANNEL12 and  Instagram – @ntaabeokuta1979

 

Show More

Related Articles

Leave a Reply

Your email address will not be published.

Back to top button